Jẹnẹsisi 15:9 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA dá a lóhùn, ó ní, “Mú ẹgbọ̀rọ̀ abo mààlúù ọlọ́dún mẹta kan, ati ewúrẹ́ ọlọ́dún mẹta kan, ati àgbò ọlọ́dún mẹta kan, ati àdàbà kan ati ọmọ ẹyẹlé kan wá.”

Jẹnẹsisi 15

Jẹnẹsisi 15:3-12