Jẹnẹsisi 15:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó gbogbo wọn wá fún OLUWA, ó là wọ́n sí meji meji, ó sì tẹ́ wọn sí ẹ̀gbẹ́ ara wọn lọ, ṣugbọn kò la àdàbà ati ẹyẹlé náà.

Jẹnẹsisi 15

Jẹnẹsisi 15:7-12