Jẹnẹsisi 15:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ẹyẹ tí wọ́n máa ń jẹ òkú ẹran rábàbà wá sí ibi tí Abramu to àwọn ẹran náà sí, ó lé wọn.

Jẹnẹsisi 15

Jẹnẹsisi 15:7-13