Jẹnẹsisi 15:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí oòrùn ń wọ̀ lọ, oorun bẹ̀rẹ̀ sí kun Abramu, ó sì sun àsùnwọra, jìnnìjìnnì mú un, òkùnkùn biribiri sì bò ó mọ́lẹ̀.

Jẹnẹsisi 15

Jẹnẹsisi 15:11-17