Jẹnẹsisi 15:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Abramu bèèrè pé, “OLUWA Ọlọrun, báwo ni n óo ṣe mọ̀ pé ilẹ̀ náà yóo jẹ́ tèmi?”

Jẹnẹsisi 15

Jẹnẹsisi 15:7-14