Jẹnẹsisi 15:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún un pé “Èmi ni OLUWA tí ó mú ọ jáde láti ìlú Uri, ní ilẹ̀ Kalidea, láti fi ilẹ̀ yìí fún ọ ní ohun ìní.”

Jẹnẹsisi 15

Jẹnẹsisi 15:5-15