Jẹnẹsisi 13:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Abramu bá sọ fún Lọti pé, “Má jẹ́ kí ìjà bẹ́ sílẹ̀ láàrin èmi pẹlu rẹ, tabi láàrin àwọn darandaran mi ati àwọn tìrẹ. Ṣebí ara kan náà ni wá?

Jẹnẹsisi 13

Jẹnẹsisi 13:2-14