Jẹnẹsisi 13:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìjà sì ń ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn darandaran Abramu ati àwọn ti Lọti. Ní àkókò náà, àwọn ará Kenaani ati àwọn ará Perisi ń gbé ilẹ̀ náà.

Jẹnẹsisi 13

Jẹnẹsisi 13:3-14