Jẹnẹsisi 13:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ ló lọ jaburata níwájú rẹ yìí, jọ̀wọ́, jẹ́ kí á takété sí ara wa. Bí o bá lọ sí apá òsì, èmi á lọ sí apá ọ̀tún, bí o bá sì lọ sí apá ọ̀tún, èmi á lọ sí apá òsì.”

Jẹnẹsisi 13

Jẹnẹsisi 13:1-13