Jẹnẹsisi 13:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni Abramu ṣe jáde kúrò ní Ijipti, ó pada lọ sí Nẹgẹbu pẹlu aya rẹ̀, ati Lọti ati ohun gbogbo tí ó ní.

Jẹnẹsisi 13

Jẹnẹsisi 13:1-9