Jẹnẹsisi 12:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Farao bá pàṣẹ fún àwọn iranṣẹ rẹ̀ nípa Abramu, wọ́n sì rí i pé Abramu jáde kúrò nílùú, ati òun ati aya rẹ̀, ati ohun gbogbo tí ó ní.

Jẹnẹsisi 12

Jẹnẹsisi 12:18-20