Jẹnẹsisi 13:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Abramu ní dúkìá pupọ ní àkókò yìí, ó ní ẹran ọ̀sìn, fadaka ati wúrà lọpọlọpọ.

Jẹnẹsisi 13

Jẹnẹsisi 13:1-12