Jakọbu 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnikẹ́ni wà láàrin yín tí ó gbọ́n, tí ó tún mòye? Kí ó fihàn nípa ìgbé-ayé rere ati ìwà ìrẹ̀lẹ̀ tí ó fi ọgbọ́n hàn.

Jakọbu 3

Jakọbu 3:4-18