Jakọbu 3:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará mi, ṣé igi ọ̀pọ̀tọ́ lè so èso olifi, tabi kí àjàrà kó so ọ̀pọ̀tọ́? Ìsun omi kíkorò kò lè mú omi dídùn jáde.

Jakọbu 3

Jakọbu 3:6-17