Jakọbu 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn tí ẹ bá ń jowú ara yín kíkankíkan, tí ẹ ní ọkàn ìmọ-tara-ẹni-nìkan, ẹ má máa gbéraga, kí ẹ má sì purọ́ mọ́.

Jakọbu 3

Jakọbu 3:7-18