Isikiẹli 28:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa ọgbọ́n ati ìmọ̀ rẹ, o ti kó ọpọlọpọ ọrọ̀ jọ fún ara rẹ, o sì kó wúrà ati fadaka jọ sinu ilé ìṣúra rẹ.

Isikiẹli 28

Isikiẹli 28:1-5