Isikiẹli 28:5 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti ní àníkún ọrọ̀ nítorí ọgbọ́n rẹ ninu òwò ṣíṣe, ìgbéraga sì ti kún ọkàn rẹ nítorí ọrọ̀ rẹ.’

Isikiẹli 28

Isikiẹli 28:1-13