Isikiẹli 27:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo gbé ohùn sókè sí ọ,wọn óo sun ẹkún kíkan kíkan.Wọn óo da erùpẹ̀ sórí wọn,wọn óo yíra mọ́lẹ̀ ninu eérú.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:24-32