Isikiẹli 27:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo fá irun orí wọn nítorí rẹ,wọn óo sán aṣọ ọ̀fọ̀ mọ́ ìdí,wọn óo sì fi ìbànújẹ́ ọkàn sọkún nítorí rẹ,inú wọn yóo sì bàjẹ́.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:23-36