Isikiẹli 27:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn atukọ̀ ni yóo jáde kúrò ninu ọkọ̀.Àwọn tí ń ṣiṣẹ́ ninu ọkọ̀ati àwọn tí ń darí ọkọ̀yóo dúró ní èbúté.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:23-34