Isikiẹli 27:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Damasku bá ọ ṣòwò nítorí ọpọlọpọ ọjà ati àwọn nǹkan olówó iyebíye tí ò ń tà, wọ́n mú ọtí waini ati irun aguntan funfun wá láti Heliboni.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:13-22