Isikiẹli 27:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Fedani ati Jafani láti Usali a máa wá fi ọtí waini pààrọ̀ ohun tí ò ń tà; wọn a kó àwọn nǹkan èlò irin wá, ati igi kasia.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:11-22