Isikiẹli 27:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Juda ati ilé Israẹli bá ọ ṣòwò: wọ́n ń kó ọkà, èso olifi, àkọ́so èso ọ̀pọ̀tọ́, oyin, òróró ati òrí wá láti fi ṣe pàṣípààrọ̀ àwọn nǹkan tí ò ń tà.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:14-23