Isikiẹli 24:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan, sàmì sí ọjọ́ òní, kọ orúkọ ọjọ́ òní sílẹ̀. Lónìí gan-an ni ọba Babilonia gbógun ti Jerusalẹmu.

Isikiẹli 24

Isikiẹli 24:1-8