Isikiẹli 24:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá mi sọ̀rọ̀ ní ọjọ́ kẹwaa, oṣù kẹwaa, ọdún kẹsan-an tí a ti wà ní ìgbèkùn, ó ní,

Isikiẹli 24

Isikiẹli 24:1-8