Isikiẹli 23:49 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo da èrè ìṣekúṣe yín le yín lórí, ẹ óo sì jìyà ẹ̀ṣẹ̀ ìbọ̀rìṣà yín. Ẹ óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA Ọlọrun.”

Isikiẹli 23

Isikiẹli 23:40-49