Isikiẹli 24:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Pa òwe yìí fún àwọn ọlọ̀tẹ̀ wọnyi kí o sì wí fún wọn pé, ní orúkọ èmi OLUWA Ọlọrun: Gbé ìkòkò kaná;bu omi sí i.

Isikiẹli 24

Isikiẹli 24:1-4