Isikiẹli 19:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí abo kinniun náà rí i pé ọwọ́ tẹ ọmọ òun,ati pé igbẹkẹle òun ti dòfo,ó mú òmíràn ninu àwọn ọmọ rẹ̀,ó tọ́ ọ di ọ̀dọ́ kinniun.

Isikiẹli 19

Isikiẹli 19:1-13