Isikiẹli 19:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ń yan kiri láàrin àwọn kinniun;nítorí ó ti di ọ̀dọ́ kinniun tí ó lágbára,ó kọ́ bí wọn tí ń ṣe ọdẹ,ó sì ń pa eniyan jẹ.

Isikiẹli 19

Isikiẹli 19:2-13