Isikiẹli 15:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Iná ni wọ́n ń fi í dá, nígbà tí iná bá jó o lórí, tí ó jó o nídìí, tí ó sì sọ ààrin rẹ̀ di èédú, ṣé ó tún ṣe é fi ṣe ohunkohun?

Isikiẹli 15

Isikiẹli 15:1-8