Isikiẹli 15:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ ẹnìkan a máa fi igi rẹ̀ ṣe ohunkohun? Àbí wọn a máa gé lára rẹ̀ kí wọn fi gbẹ́ èèkàn tí wọ́n fi ń so nǹkan mọ́lẹ̀?

Isikiẹli 15

Isikiẹli 15:1-4