Isikiẹli 15:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó wà ní odidi, kò wúlò fún nǹkankan. Nígbà tí iná ti jó o, tí ó ti di èédú, ṣé eniyan tún lè fi ṣe ohunkohun?”

Isikiẹli 15

Isikiẹli 15:2-8