Isikiẹli 11:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, àwọn Kerubu bá gbéra, wọ́n fò, pẹlu àgbá, ní ẹ̀gbẹ̀ẹ̀gbẹ́ wọn; ìtànṣán ògo OLUWA Ọlọrun Israẹli sì wà lórí wọn.

Isikiẹli 11

Isikiẹli 11:16-25