Isikiẹli 11:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ògo OLUWA gbéra kúrò láàrin ìlú náà, ó sì dúró sórí òkè tí ó wà ní apá ìhà ìlà oòrùn ìlú náà.

Isikiẹli 11

Isikiẹli 11:20-25