Isikiẹli 11:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn n óo fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ jẹ àwọn tí ọkàn wọn ń fà sí àwọn ohun ẹ̀gbin ati ìríra. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Isikiẹli 11

Isikiẹli 11:13-25