Isikiẹli 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

kí wọ́n lè máa rìn ninu ìlànà mi, kí wọ́n sì lè máa pa òfin mi mọ́. Wọn óo jẹ́ eniyan mi, èmi náà óo sì jẹ́ Ọlọrun wọn.

Isikiẹli 11

Isikiẹli 11:10-23