Isikiẹli 11:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, mo sọ pé, n óo fún wọn ní ọkàn kan, n óo fi ẹ̀mí titun sí wọn ninu. N óo yọ ọkàn òkúta kúrò láyà wọn, n óo sì fún wọn ní ọkàn ẹran;

Isikiẹli 11

Isikiẹli 11:9-20