Ìfihàn 20:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gba gbogbo ìbú ilẹ̀ ayé, wọ́n wá yí àwọn eniyan Ọlọrun ká ati ìlú tí Ọlọrun fẹ́ràn. Ni iná bá sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run, ó bá jó wọn run patapata.

Ìfihàn 20

Ìfihàn 20:7-13