Ìfihàn 20:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo wá tún jáde lọ láti máa tan àwọn eniyan jẹ ní igun mẹrẹẹrin ilẹ̀ ayé. Yóo kó gbogbo eniyan Gogu ati Magogu jọ láti jagun, wọn óo pọ̀ bí iyanrìn etí òkun.

Ìfihàn 20

Ìfihàn 20:1-15