Ìfihàn 20:10 BIBELI MIMỌ (BM)

A bá ju Èṣù tí ó ń tàn wọ́n jẹ sinu adágún iná tí a fi imí-ọjọ́ dá, níbi tí ẹranko náà ati wolii èké náà wà, tí wọn yóo máa joró tọ̀sán-tòru lae ati laelae.

Ìfihàn 20

Ìfihàn 20:6-14