Ìfihàn 20:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá rí ìtẹ́ funfun ńlá kan ati ẹni tí ó jókòó lórí rẹ̀. Ayé ati ọ̀run sálọ fún un, a kò rí ààyè fún wọn mọ́.

Ìfihàn 20

Ìfihàn 20:10-15