Ìfihàn 20:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá rí angẹli kan tí ó ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ wá, ó mú kọ́kọ́rọ́ kànga tí ó jìn pupọ náà lọ́wọ́ ati ẹ̀wọ̀n gígùn.

Ìfihàn 20

Ìfihàn 20:1-4