Ìfihàn 19:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n fi idà tí ó wà lẹ́nu ẹni tí ó gun ẹṣin funfun pa àwọn yòókù. Gbogbo àwọn ẹyẹ bá ń jẹ ẹran-ara wọn ní àjẹrankùn.

Ìfihàn 19

Ìfihàn 19:11-21