Ìfihàn 20:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá ki Ẹranko Ewèlè náà mọ́lẹ̀, ejò àtijọ́ náà tíí ṣe Èṣù tabi Satani, ó fi ẹ̀wọ̀n dè é fún ẹgbẹrun ọdún.

Ìfihàn 20

Ìfihàn 20:1-7