Ìfihàn 17:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹranko tí ó ti wà láàyè rí, tí kò sí mọ́, ni ẹkẹjọ, ṣugbọn ó wà ninu àwọn meje tí ń lọ sinu ègbé.

Ìfihàn 17

Ìfihàn 17:8-18