Ìfihàn 17:12 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn ìwo mẹ́wàá tí o rí jẹ́ ọba mẹ́wàá. Ṣugbọn wọn kò ì tíì joyè. Wọn óo gba àṣẹ fún wakati kan, àwọn ati ẹranko náà ni yóo jọ lo àṣẹ náà.

Ìfihàn 17

Ìfihàn 17:5-18