Ìfihàn 17:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Marun-un ninu wọn ti kú. Ọ̀kan wà lórí oyè nisinsinyii. Ọ̀kan yòókù kò ì tíì jẹ. Nígbà tí ó bá jọba, àkókò díẹ̀ ni yóo ṣe lórí oyè.

Ìfihàn 17

Ìfihàn 17:6-11