Ìfihàn 17:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọ̀rọ̀ yìí gba ọgbọ́n. Orí meje tí ẹranko náà ní jẹ́ òkè meje tí obinrin náà jókòó lé lórí. Wọ́n tún jẹ́ ọba meje.

Ìfihàn 17

Ìfihàn 17:3-17