Ìfihàn 16:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbọ́ ohùn líle kan láti inú Tẹmpili tí ó sọ fún àwọn angẹli meje náà pé, “Ẹ lọ da àwọn àwo meje tí ó kún fún ibinu Ọlọrun sinu ayé.”

Ìfihàn 16

Ìfihàn 16:1-5