Ìfihàn 15:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú Tẹmpili wá kún fún èéfín ògo Ọlọrun ati ti agbára rẹ̀. Kò sí ẹni tí ó lè wọ inú Tẹmpili títí tí àwọn àjàkálẹ̀ àrùn meje ti àwọn angẹli meje náà fi parí.

Ìfihàn 15

Ìfihàn 15:1-8